Òní l’ọpẹ ọdún méjìlá tí ìràwọ ọsán ti ba àgbà lérù Dagrin asọ̀rọ̀ nínú orin ṣe pẹkí ọlọjọ rẹ nínú ìjàmbá ọkọ.
Gbajúgbajà Olórin, Olaitan Oladapo Olanipekun, Ti ọpọ eyan npè ni Dagrin, tabi Akogun Okunrin Ogun, Barrack ȍ’grin, Lerikuwere, Egbeda 1, C.Ε.Ȍ Omo ita.
Àbí ni oṣù kẹwa ọdún 1984 ni agbègbè
He was Born October 1984 in an Ìdí Àràbà area called ókúrò ní ilé ìwé latàrí ẹ̀yìn tó tòsí làrin awọn akẹgbẹ rẹ ní ilé ìwé.
Ó ní A1 nínú ìdánwò àṣẹ kágbá, o sì félì gbogbo èyí tó kù.
Ọmọ Èkó ni, o sí ti gbé òpòlopò àdúgbò l’eko, ìfẹ tó ní sí Yorùbá l’omu ko bẹrẹ sí ní fi èdè Yorùbá Rap nínú ìrìn, bi ti 2PAC, Fela Kuti àti bẹbẹ lọ.
Ikú pá láì pé ọjọ, Òkú ni ọjọ kejilelogun osu Kerin ọdún pril 2010 ní dédé ago mẹfa irọlẹ ni ilé ìwòsan Luth,Idi-Araba Surulere l’eko.
Kí ọlọrun tẹ sí afẹfẹ rere. Àmín





Leave a Reply