Kábíyèsí ikú bàbá yèyé Alaafin Oyo Ọba Làmídì Adéyemí wọ àjà lànà ọjọ ẹtì ọjọ kejilelogun oṣù kẹrin ọdún 2022 ni ilé ìwòsan olukọni Afẹ Babalola ní ìlú Ado Ekiti. Gẹgẹ bí ìròyìn takò jọ.
Wọn ti gbé bàbá darí si àfín làró òní Sátidé, bi ohun tí ọmọ alafin ọmọ ọba Tunde fi léde.
Ètò orò fún oba to wọ àjà sí ti bẹrẹ.
Àbí ọba Làmídì Adéyemí ni ọjọ keedogun oṣù kẹwa ọdún 1938. Ọmọ Alaafin Adéyemí Kejì ni ọba Làmídì, ogori ààpèrè lẹhin ọba Gbadegesin Ladigbolu l’ọdun 1970, wọn sì dé ladé ni ọjọ kẹrinla oṣù kini ọdún 1971.
Ọdún Méjìlélaadota ni ọba Làmídì
Adéyemí ló lórí ààpèrè awọn baba won





Leave a Reply