Advertisement

A ni lo èròrí tuntun tíó mu Nàìjíría kúrò nínú ìṣòro ọrọ ajé àti ìpènijà lẹka òṣèlú kìí Naijiria le bọsipọ – Bolaji Abdullahi

Mínísítà tẹlẹ rí fún ọ̀dọ́ atí ere ìdárayá tíì o tún jẹ olùdíje du ipò ṣínétọ̀ labẹ àsìá ẹgbẹ òṣèlú People’s Democratic Party (PDP), Mall. Abdulganiy Bolaji Abdullahi ṣe àlàyé ìdí fún èròrí tuntun tíó mu Nàìjíría jáde kúrò ninu ìṣòro ọrọ ajé àwùjọ àti tíì oselu ti a nkoju láti mú ohun gbogbo bọsipọ.

Ọ̀jìnmì akọ̀ròyìn ati gbajúgbajà Onkọ̀wé ọ́un sọ ọpọ ọrọ níbi ifi-ori ori okòó sọodúnrún pẹlu awọn akọ̀ròyìn lóri ìtàkùn ayélujára Association Of Kwara Online Media Practitioners (ASKOMP) ni ọjọ ajé.

Abdullahi ní ìkóríta ìwà láàyè orílẹ-èdè yi, awọn èniyàn ko gbọdọ dẹyẹ sí ipò òṣèlú látàrí pe wọn fẹ yọ èpò láàrin alikamon biko ṣe pé kí a gbaradì lati ṣa ipá èyí níí yíò mu ohun gbogbo bọsipọ.

O ká àwọn ètò rẹ bi ohun bá di ṣínétọ̀ tíó yíò s’oju ẹkùn ìhà àrin gùngùn Ìpínlè Kwara lati ṣe òfin, rọgbun sí apá awọn ará ẹkun oun lẹka ètò ẹkọ ati ìdàgbàsókè ìsèmí ìjẹ́ ọmọ ènìyàn

Lórí ọrọ àìní ètò àbò to múyán ti orílẹ-èdè yi nkoju orílè-èdè, o sọ ni pa ìpènijà òun, o sí ni e bá rara tí ìjọba ba le ni ànfàní láti ṣe ètò àbò wọn ni ọnà tí o wù wọn, láti ní oga ọmọ ogun alabó fún ra wọn.

Ó sọrọ ní pa bi o ṣe le ṣe abojuto ọrọ ẹgbẹ ati ti awọn ara ìlú tí wọn ddioohu ni ìgbà tí ìpènijà bàa súyọ. O ni ẹgbẹ ohun jẹ ẹgbẹ tíì o ni èrò ilu lọkàn rẹ, pé ohun o ro péé iru ẹ le ṣẹlẹ.

F’èsì sí ibere, lórí ìrìn àjò rẹ gẹgẹ bí Commissioner fún ètò ẹkọ ni 6ipinle Kwara lórí aesọ ọrọ kan pe o gba olukọ kan létí, O ni ohun o ṣe bẹ, pe ati ìgbà náà ni ohun tí npè fún mọlẹbi olukọ náà láti wa jẹri, tíó ohun bẹrẹ pe ilé ìwé wo ni iṣẹlẹ náà ni ṣẹlẹ, awọn wo ni alábá a ok ṣiṣẹ olukọ náà àti wípé tan ọgá ilé ìwé náà

Gẹgẹ bi comisona tẹlẹri, iṣẹjoba ohun, lo fi òpin sí jíjẹ owó oṣù àwọn olùkọ SUBEB ati TESCOM mọlẹ ni ìpínlè Kwara, o ni ṣaaju awon kan ma ngé owó oṣù àwọn olùkọ látàrí pe won gba owó oṣù pẹlu ọwọ, o ni ohun lohun kan nípa fún wọn láti sí akọtọ owó ìfowópamọ. O ni inú iru àwọn olùkọ ti o dènà ati ma gé owó olowo yẹn o ni dùn, o ṣe àlàyé pe ore ni ohun ṣe àwọn olùkọ pe ohun ko ṣe wọn torí awọn akẹkọ òun sì ni, o ni ìdánwò wọn ni èsì ìgbìyànjú náà.

About Author

Share this News:

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *