Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara Mallam AbdulRahman Abdulrazaq ni ọpọ ọrọ ṣá dede bẹẹle le lórí, ọpọ ni o wa ni Osogbo ni ibi ti ọpọ awọn àgbà àtijó Abdulrazaq ọmọ ẹgbẹ APC ti lọ ṣe atilẹyin fún Gómìnà Adegboyega Oyekola lórúkọ ẹgbẹ ni igbaradi ètò ìdìbò Ìpínlè ohun tíó wáyé ni ọjọ Sátidé.
Àwòrán tí ari sí ṣe àfihàn Gómìnà ti o joko pẹkipẹki pẹlu are àjọ to nmoju to bóòlù alafese gbá lórílè-edè yi, Amaju Pinnick ni pápá ìseré nlá ti ogbalejo
Ifesewonse náà ni Casablanca lorilede Morrocco.
Òwúyẹ kan ni Gómìnà bá awọn ìkọ ẹgbẹ àgbá bóòlù Super Falcon ti orile-ede yi sọrọ sáà ju ìfagágbága náà, Àmín ayo kan ni Falcons fi yọwọ orile-ede Cameroon kuro nínú ìdíje náà, wọn ti peregede sí ipele ti o kangun sí àṣe kagba ìdíje náà, wọn si tún ti yan yo lati lo soju ile adúláwọ̀ ninu ìdíje ifeye àgbàláyé.





Leave a Reply