Advertisement

Ìdìbò Abẹle APC: Pasito Tunde Bakare kò rí ìbò kankan mú. Kò sí ẹnìkankan tó dìbò fún-un.

Ni ibí ètò ìdìbò abẹnu ẹgbẹ òṣèlú APC ti o waye loni, kayefi nlá lo jẹ pe lẹyin ọpọ atotonu ti gbogbo awọn olùdíje ṣe ṣáájú kí ètò ìdìbò to bere.

Sinetọ Ahmed Bola Tinubu lo gbe igba oroke ni ibí ètò ìdìbò náà.

Wọn sì ti gbé àsìá olùdíje dupo ààrẹ ẹgbẹ òun fún.

Ẹwẹ, Bola Tinubu sọ pe awọn kan ati awọn ileeṣẹ iroyin kan ti lero pe ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, yoo daru nitori idibo abẹle.

“Oju ti awọn to ti kọwe iku, kan posi, gbẹ saare ẹgbẹ oṣelu APC.”

O ni opin ẹgbẹ PDP ti de bayii ti oun ti di oludije fun ẹgbẹ PDP.

O ni ko si oniṣẹ okunkun kankan, tabi alayọjuran to le da Naijiria pada si oko wahala.

About Author

Share this News:

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *