
Ìkọ ẹgbẹ àgbá bóòlù Kwara United pàá ìkọ ẹgbẹ àgbá bóòlù Rivers United lẹkun ni ìlú Ilorin ni igba ti wọn pàdé nínú iṣii Kejì ìfagágbága wọn tó wáyé ni pápá ìseré ti ilu Ilorin.
Àmín Ayò Méjì sí ọdọ ni ìfagágbága náà yọrí sí boti e jépé Rivers United lokoko min awọn kan ki Kwara United to fi meji ko wan sita bi ọmọ ọjọ mẹjọ




Leave a Reply