Ọgbẹni Clement Kumbi Titiloye alága fun ìkọ ẹgbẹ agbá bóòlù Kwara United ti ìlú Ilorin jẹjẹ atilẹyin to gbopan fún eré ìdárayá follibọọlu.
Oni agbùdò pàdà si ẹsẹ kuku to ba jépé lóòtó ni a fẹ ìdàgbàsókè to muyan Lágbo eré ìdárayá.
Ninu ọrọ rẹ, o se àpèjúwe pe, agbùdò mu wa lati èwe ki asi ma ṣe kori yá ati àtìlẹ́yìn fún wọn
Òní oda ohun lójú pé, atilẹyin yi, yíò ṣe ìwúrí fún àwọn ògo wẹẹrẹ náà.

Ógbé òsubà ràndẹ̀ fún àwọn tó ṣe agbáteru idije náà àti igbimọ ere ìdárayá tíó se atilẹyin fún ìràn náà.
#Adexsports





Leave a Reply