ní ọjọ sátidé, ni ìgbà tí ìkọ ẹgbẹ àgbá bóòlù Manchester United bá ikọ̀ ẹgbẹ àgbá bóòlù Brighton & Hove Albion ni àlejò ninu ìdíje EPL, Man U ṣe àgbákò lọwọ Brighton, wọn pa iná ile Man Í wọn sì tún pa iná ayé wọn. Mẹrin sí ọdọ ni Man u gbà
Èyí ní bí ìrònú ṣe sọ orí àgbà kodò l’ọjo Àbá mẹta Sátidé





Leave a Reply