Kunle Adeyanju, ọmọ Yorùbá tó ń fi alùpùpù rìn láti London lo sí Eko ti dé sí Afrika o.
📸: Twitter/ Kunle Adeyanju
Kunle ti dé sí Morrocco bayi pẹlu manṣini lati òke òkun.


Website: http://latestcitynews.com.ng/
Latest City News is an online news platform that is proudly providing high quality professionalism.
Leave a Reply