Ààrẹ ẹgbẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè àti àṣà yorùbá ẹka Ìpínlè Kwara, Adeoye Matiu Bukola ranṣẹ ìkíni sí gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ èdè àti àṣà yorùbá jákè-jádò orile-ede Nàìjíríà fún rírí oṣù tuntun ti Islam, Ramadan 1444H.
Bukola, pè fún, àjọ ṣe pọ tíó dan l’arin awọn akẹ́kọ̀ọ́ ní orílè èdè yìí, ó ní èyí yó dẹ́kun ẹlẹ́yà mẹ̀yà ní àwùjọ waa.
Ó ṣe àlàyé sí wájú síi ìdí tí a fi ní ló ìbẹ̀rù Ọlọ́hun lórí gbogbo àdáwọ́lé iṣẹ́ waa , ó ní èyí yó lè ma tọ ẹsẹ̀ waa sí ipa ọgbọ́n .
Ààrẹ, ní gẹ́gẹ́ bíi ọ̀dọ́ , a gbọdọ̀ jẹ́ àwòkọ́ṣe rere ní àwùjọ waa.
Ó ní, ìdí tí akẹ́kọ̀ọ́ ṣe gbọdọ̀ gbá jú mọ́ ẹ̀kọ́ kọjá kíkà nìkan, bí kò ṣe láti le ní ìran ọjọ́ iwájú ire fún ara waa.
Ó gbàdúrà wípé àṣe yè ni a ó ṣe Láṣẹ Èdùmàrè.





Leave a Reply